Metusela

“Enoku si wà li ọgọta ọdún o le marun, o si bí Metusela. Lẹ́yìn tí ó bí Metusela, Enoku bá Ọlọrun
rìn ní ọọdunrun ọdún ó sì bí àwọn ọmọkunrin ati ọmọbinrin. Gbogbo ọjọ́ ayé Enoku jẹ́ ọọdunrun
ó lé marun-un ó lé marun-un. Enoku si bá Ọlọrun rìn; kò sì sí, nítorí Ọlọ́run mú un.” Gẹ́nẹ́sísì
5:21-24 .
“Nípa ìgbàgbọ́ ni a mú Énọ́kù lọ tí kò fi rí ikú, “a kò sì rí i, nítorí Ọlọ́run ti mú un; nítorí kí wọ́n tó
mú un, ó ti jẹ́rìí sí i pé ó wu Ọlọ́run.” Heb 11:5.

Similar Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *